Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 22 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَتِلۡكَ نِعۡمَةٞ تَمُنُّهَا عَلَيَّ أَنۡ عَبَّدتَّ بَنِيٓ إِسۡرَٰٓءِيلَ ﴾
[الشعراء: 22]
﴿وتلك نعمة تمنها علي أن عبدت بني إسرائيل﴾ [الشعراء: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé ìyẹn ni ìdẹ̀ra tí ò ń ṣe ìrègún rẹ̀ lé mi lórí. Pé ó sọ àwọn ọmọ ’Isrọ̄’īl di ẹrú (ńkọ́) |