Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 29 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ لَئِنِ ٱتَّخَذۡتَ إِلَٰهًا غَيۡرِي لَأَجۡعَلَنَّكَ مِنَ ٱلۡمَسۡجُونِينَ ﴾
[الشعراء: 29]
﴿قال لئن اتخذت إلها غيري لأجعلنك من المسجونين﴾ [الشعراء: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Dájúdájú tí o bá fi lè jọ́sìn fún ọlọ́hun kan yàtọ̀ sí mi, dájúdájú mo máa sọ ọ́ di ara àwọn ẹlẹ́wọ̀n.” |