Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 44 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿إِلَّا رَحۡمَةٗ مِّنَّا وَمَتَٰعًا إِلَىٰ حِينٖ ﴾
[يسٓ: 44]
﴿إلا رحمة منا ومتاعا إلى حين﴾ [يسٓ: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àfi (kí Á fi) ìkẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Wa (yọ wọ́n jáde, kí A sì tún fún wọn ní) ìgbádùn ayé títí di ìgbà díẹ̀ |