Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 57 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿أَوۡ تَقُولَ لَوۡ أَنَّ ٱللَّهَ هَدَىٰنِي لَكُنتُ مِنَ ٱلۡمُتَّقِينَ ﴾
[الزُّمَر: 57]
﴿أو تقول لو أن الله هداني لكنت من المتقين﴾ [الزُّمَر: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí kí ó má baà wí pé: "Tí ó bá jẹ́ pé Allāhu fi ọ̀nà mọ̀ mí ni, dájúdájú èmi ìbá wà nínú àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) |