Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 16 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿يَوۡمَ نَبۡطِشُ ٱلۡبَطۡشَةَ ٱلۡكُبۡرَىٰٓ إِنَّا مُنتَقِمُونَ ﴾
[الدُّخان: 16]
﴿يوم نبطش البطشة الكبرى إنا منتقمون﴾ [الدُّخان: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọjọ́ tí A óò gbá (wọn mú) ní ìgbámú t’ó tóbi jùlọ; dájúdájú Àwa yóò gba ẹ̀san ìyà (lára wọn) |