Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 15 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿إِنَّا كَاشِفُواْ ٱلۡعَذَابِ قَلِيلًاۚ إِنَّكُمۡ عَآئِدُونَ ﴾
[الدُّخان: 15]
﴿إنا كاشفوا العذاب قليلا إنكم عائدون﴾ [الدُّخان: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa máa gbé ìyà náà kúrò fún ìgbà díẹ̀. Dájúdájú ẹ̀yin yóò tún padà (sínú àìgbàgbọ́) |