Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 24 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿وَٱتۡرُكِ ٱلۡبَحۡرَ رَهۡوًاۖ إِنَّهُمۡ جُندٞ مُّغۡرَقُونَ ﴾
[الدُّخان: 24]
﴿واترك البحر رهوا إنهم جند مغرقون﴾ [الدُّخان: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì fi agbami odò sílẹ̀ ní yíyanu sílẹ̀ bẹ́ẹ̀. Dájúdájú àwọn ni ọmọ ogun tí A máa tẹ̀rì sínú agbami |