Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 17 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿وَٱلَّذِينَ ٱهۡتَدَوۡاْ زَادَهُمۡ هُدٗى وَءَاتَىٰهُمۡ تَقۡوَىٰهُمۡ ﴾
[مُحمد: 17]
﴿والذين اهتدوا زادهم هدى وآتاهم تقواهم﴾ [مُحمد: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó sì tẹ̀lé ìmọ̀nà, (Allāhu) ṣàlékún ìmọ̀nà fún wọn. Ó sì máa fún wọn ní ìbẹ̀rù wọn (nínú Allāhu) |