Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 23 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَقَالَ قَرِينُهُۥ هَٰذَا مَا لَدَيَّ عَتِيدٌ ﴾
[قٓ: 23]
﴿وقال قرينه هذا ما لدي عتيد﴾ [قٓ: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Mọlāika) alábàárìn rẹ̀ yóò sọ pé: "Èyí ni ohun tí ń bẹ ní ọ̀dọ̀ mi (gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀) |