×

Ti Allahu ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o 53:31 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Najm ⮕ (53:31) ayat 31 in Yoruba

53:31 Surah An-Najm ayat 31 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 31 - النَّجم - Page - Juz 27

﴿وَلِلَّهِ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَمَا فِي ٱلۡأَرۡضِ لِيَجۡزِيَ ٱلَّذِينَ أَسَٰٓـُٔواْ بِمَا عَمِلُواْ وَيَجۡزِيَ ٱلَّذِينَ أَحۡسَنُواْ بِٱلۡحُسۡنَى ﴾
[النَّجم: 31]

Ti Allahu ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o wa ninu ile nitori ki O le san awon t’o se ise aburu ni esan ohun ti won se nise ati nitori ki O le san awon t’o se ise rere ni esan rere

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولله ما في السموات وما في الأرض ليجزي الذين أساءوا بما عملوا, باللغة اليوربا

﴿ولله ما في السموات وما في الأرض ليجزي الذين أساءوا بما عملوا﴾ [النَّجم: 31]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ti Allāhu ni ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ohunkóhun t’ó wà nínú ilẹ̀ nítorí kí Ó lè san àwọn t’ó ṣe iṣẹ́ aburú ní ẹ̀san ohun tí wọ́n ṣe níṣẹ́ àti nítorí kí Ó lè san àwọn t’ó ṣe iṣẹ́ rere ni ẹ̀san rere
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek