Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 37 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿فَإِذَا ٱنشَقَّتِ ٱلسَّمَآءُ فَكَانَتۡ وَرۡدَةٗ كَٱلدِّهَانِ ﴾
[الرَّحمٰن: 37]
﴿فإذا انشقت السماء فكانت وردة كالدهان﴾ [الرَّحمٰن: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, nígbà tí sánmọ̀ bá fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, ó sì máa pọ́n wá wẹ̀ bí epo pupa |