Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 34 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿إِنَّ لِلۡمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمۡ جَنَّٰتِ ٱلنَّعِيمِ ﴾
[القَلَم: 34]
﴿إن للمتقين عند ربهم جنات النعيم﴾ [القَلَم: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra wà fún àwọn olùbẹ̀rù lọ́dọ̀ Olúwa wọn |