Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 12 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿لِنَجۡعَلَهَا لَكُمۡ تَذۡكِرَةٗ وَتَعِيَهَآ أُذُنٞ وَٰعِيَةٞ ﴾
[الحَاقة: 12]
﴿لنجعلها لكم تذكرة وتعيها أذن واعية﴾ [الحَاقة: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí kí Á lè fi ṣe ìrántí fun yín àti nítorí kí etí t’ó ń ṣọ́ n̄ǹkan lè ṣọ́ ọ |