Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 11 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿إِنَّا لَمَّا طَغَا ٱلۡمَآءُ حَمَلۡنَٰكُمۡ فِي ٱلۡجَارِيَةِ ﴾
[الحَاقة: 11]
﴿إنا لما طغى الماء حملناكم في الجارية﴾ [الحَاقة: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú nígbà tí omi tayọ ẹnu-àlà. A gbe yín gun ọkọ̀ ojú-omi |