Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 16 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَٱنشَقَّتِ ٱلسَّمَآءُ فَهِيَ يَوۡمَئِذٖ وَاهِيَةٞ ﴾
[الحَاقة: 16]
﴿وانشقت السماء فهي يومئذ واهية﴾ [الحَاقة: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé sánmọ̀ yó fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ. Ó sì máa fúyẹ́ gẹgẹ ní ọjọ́ yẹn |