Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 18 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿يَوۡمَئِذٖ تُعۡرَضُونَ لَا تَخۡفَىٰ مِنكُمۡ خَافِيَةٞ ﴾
[الحَاقة: 18]
﴿يومئذ تعرضون لا تخفى منكم خافية﴾ [الحَاقة: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ yẹn, wọn yóò máa ṣẹ́rí yín wá (fún ìṣírò-iṣẹ́). Kò sì níí sí àṣírí yín kan t’ó máa pamọ́ (fún Wa) |