×

Nitori naa, fi won sile ki won maa so isokuso (won), ki 70:42 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Ma‘arij ⮕ (70:42) ayat 42 in Yoruba

70:42 Surah Al-Ma‘arij ayat 42 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 42 - المَعَارج - Page - Juz 29

﴿فَذَرۡهُمۡ يَخُوضُواْ وَيَلۡعَبُواْ حَتَّىٰ يُلَٰقُواْ يَوۡمَهُمُ ٱلَّذِي يُوعَدُونَ ﴾
[المَعَارج: 42]

Nitori naa, fi won sile ki won maa so isokuso (won), ki won si maa sere titi won yoo fi pade ojo won ti A n se ni adehun fun won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فذرهم يخوضوا ويلعبوا حتى يلاقوا يومهم الذي يوعدون, باللغة اليوربا

﴿فذرهم يخوضوا ويلعبوا حتى يلاقوا يومهم الذي يوعدون﴾ [المَعَارج: 42]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Nítorí náà, fi wọ́n sílẹ̀ kí wọ́n máa sọ ìsọkúsọ (wọn), kí wọ́n sì máa ṣeré títí wọn yóò fi pàdé ọjọ́ wọn tí À ń ṣe ní àdéhùn fún wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek