Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 5 - نُوح - Page - Juz 29
﴿قَالَ رَبِّ إِنِّي دَعَوۡتُ قَوۡمِي لَيۡلٗا وَنَهَارٗا ﴾
[نُوح: 5]
﴿قال رب إني دعوت قومي ليلا ونهارا﴾ [نُوح: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Olúwa mi, dájúdájú èmi pe ìjọ mi ní òru àti ní ọ̀sán |