Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qiyamah ayat 13 - القِيَامة - Page - Juz 29
﴿يُنَبَّؤُاْ ٱلۡإِنسَٰنُ يَوۡمَئِذِۭ بِمَا قَدَّمَ وَأَخَّرَ ﴾
[القِيَامة: 13]
﴿ينبأ الإنسان يومئذ بما قدم وأخر﴾ [القِيَامة: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa fún ènìyàn ní ìró ní ọjọ́ yẹn nípa ohun t’ó tì síwájú (nínú iṣẹ́ rẹ̀) àti ohun t’ó fi kẹ́yìn (nínú orípa iṣẹ́ rẹ̀) |