Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 31 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿وَإِذَا ٱنقَلَبُوٓاْ إِلَىٰٓ أَهۡلِهِمُ ٱنقَلَبُواْ فَكِهِينَ ﴾
[المُطَففين: 31]
﴿وإذا انقلبوا إلى أهلهم انقلبوا فكهين﴾ [المُطَففين: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá sì padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn wọn, wọ́n á padà tí wọn yóò máa ṣe fáàrí |