Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 27 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿لَا يَسۡبِقُونَهُۥ بِٱلۡقَوۡلِ وَهُم بِأَمۡرِهِۦ يَعۡمَلُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 27]
﴿لا يسبقونه بالقول وهم بأمره يعملون﴾ [الأنبيَاء: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kì í ṣíwájú Allāhu sọ̀rọ̀. Wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àṣẹ Rẹ̀ |