Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 29 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿قَالُواْ بَل لَّمۡ تَكُونُواْ مُؤۡمِنِينَ ﴾
[الصَّافَات: 29]
﴿قالوا بل لم تكونوا مؤمنين﴾ [الصَّافَات: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn àlùjànnú) wí pé: "Rárá o (àwa kọ́), ẹ̀yin ni ẹ kò jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo |