Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Alaq ayat 19 - العَلَق - Page - Juz 30
﴿كـَلَّا لَا تُطِعۡهُ وَٱسۡجُدۡۤ وَٱقۡتَرِب۩ ﴾
[العَلَق: 19]
﴿كلا لا تطعه واسجد واقترب﴾ [العَلَق: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Rárá o, má ṣe tẹ̀lé tirẹ̀. Forí kanlẹ̀ (kí o kírun), kí o súnmọ́ (Allāhu) |